Prayers in Ede Idaca | Dominik M. Ramík Dominik M. Ramík
Česky
En français


Prayers in Ede Idaca (ìdàáshà)

list Show the list of prayers in all languages

autorenewLoading the map
 Vigorous language (126)   Endangered language (12)   Moribund / extinct language (4)
 Speaker outside of the usual language range


Do you like this project? Support it by a donation via PayPal.

Ede Idaca (ìdàáshà)

face Speaker: Innocent (Benin, Dassa-Zoumé)
add_circle_outline Church: Roman Catholic Church
translate Info about the language: text_fields Script: Latin (info on ScriptSource)
import_contacts Source of the text: The text comes from official church sources.

Sign of the Cross in Ede Idaca (ìdàáshà)

play_circle_filled
Lí eríkɔ Iba, Ɔma àti Ɛ̀mí mímá! Àamí!

Lord's Prayer in Ede Idaca (ìdàáshà)

play_circle_filled
Iba wa yèé wà l'ɔ́run ɛ̀,
ònìyàn kpóó kó teríba f'órúkɔ ɛ̀ɛ.
Oyè ɛ kó kárídì kpóó.
Yebá àà she awù ɛ l'ɔ́run ɛ̀,
kójí bɛ́ɛ̀ l'áyé lí lèyí.
Fú ni l'íjɛ ɔjɔ́kɔ́jɔ́ wa l'oní.
Fu ɛjɔ́ wa àan fu ra ni,
yebá àa ɛ́ fu ra ɔni yèé shɛ̀ lá ni àan ɛ̀.
Má bi shí àa kójì lí ìdánwò èshù,
o sɛ̀ gba ni là kóò lí iwun búburú.
Àmí

Hail Mary in Ede Idaca (ìdàáshà)

play_circle_filled
N kín ɛ Maríà,
ò kún f'óre ɔ̀fɛ́,
olúwa wà ùungbɛ̀ɛ gbo.
À wúre fɛ́ɛ kpere olobìrin àn kpóó,
à sɛ̀rɛ́ wúre fí Jesúù èso inú ɛ̀ɛ.
Maríà mímá ìnà Ɔlɔ́run,
gbàdúwà fí ni, àa ashe iwun búburú an
ti lísìín títí dìrè ikú wa.
Àmí

Apostles' Creed in Ede Idaca (ìdàáshà)

play_circle_filled
N gba Ɔlɔ́run gbɔ́, Iba atóláiwunkpóó,
ɛlɛ́dá ɔ̀run kánná ayé,
n sɛ̀rɛ́ gba Ɔma ɛ̀ Jesu Krístù òbú Olúwa wa,
yèé à l'éfùn ɛ̀ gbàlí iwun shíshe Ɛ̀mí Mímá,
shí Maríà agbélɔ́wɔ́ bí u.
Ó r'ɔ́kpɔ l'ɔ́wɔ́ Pónsu Pilátù,
à kàn ú má ègìdáàbú, ó kú, shí à rì ú,
ó lɔ l'íkpò òkú an. L'ɔ́jɔ́kɛ́ta ɔ́,
ó jí kóò lɛ́ɛrin òkú an, ó gòkè ɔ̀run,
ó jokó l'ɔ́wɔ́ ɔ̀tán Ɔlɔ́run Iba atóláiwunkpóó.
Ibi ɛ kóti kó wa wíjɔ́ bá ɔni àyɛ̀ an
kánná ɔnikú anɛ̀.
N gba ìjɔ Ɛ̀mí Mímá gbɔ́,
n gba ìjɔ Katolíkì Mímá gbɔ́,
n gba ìkpéré ònìyàn mímá an gbɔ́,
n gba ɛjɔ́ fúrurani gbɔ́,
n gba jíjí àa ònìyàan gbɔ́,
n gba ayé matán gbɔ́.
Àmí
list Show the list of prayers in all languagesVanuatu